Asawa July 4,2022
New Yoruba chat and calling App, now available on Apple and Playstore.
KÍLÓŃLỌ?
Kére o! Èyí ni láti fi tó o yín létí pé àwa ọmọ Yorùbá ti ṣe àgbéjáde aápù tuntun kan tó lè ṣe ohun tí ẹ̀ ń fi whatsapp ṣe. “Kílóńlọ” ni orúkọ aápù náà. Ẹ lè gbà á lórí playstore tàbí applestore yín. Ààbò tó péye wà fún data yín lórí Kílóńlọ. Tẹni-n-tẹni. “Kílóńlọ” wà fún gbogbo ènìyàn jàkèjádò àgbáńlá ayé.
Tẹ líǹkì ìsàlẹ̀ yìí láti gba aápù “Kílóńlọ” sórí ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ rẹ.
Fún ẹ̀rọ-ìbánisọ̀rọ̀ Android, gba aápù náà níbi:
https://play.google.com/store/apps/details?id=com.kilonlo.chat
Fún iPhone, gbà á níbi:
https://apps.apple.com/in/app/kilonlo/ID1629061716
Ẹ ṣeun púpọ̀. 🙏🏿
Ire o!
This is to bring to your notice that the Yorùbá people have invented a new “Application” that can perform similar function with WhatsApp. It is called Kílóńlọ? (What’s happening? or what’s trending?) You can download it on your Android phone via playstore and on iPhone via applestore. Maximum protection guaranteed and it consumes less Data.
Kílóńlọ (what’s trending) belongs to us both home and afar, let’s embrace it all.
For Android follow the link: https://play.google.com/store/apps/details?id=com.kilonlo.chat
For iPhone, download through: https://apps.apple.com/in/app/kilonlo/ID1629061716
Thank you. 🙏🏿
You can use this app to record both video and audio
You can use this app to mark messages as you read or unmark
Proudly Yoruba chat app.